Ní ọ̀sẹ̀ yìí lórí ètò Ìwòyé : Awọn Ọlọ́pàá ti mú Ìyábọ̀ Ṣowùnmí tí ó fẹ́ gbé oògùn olóró fun omo rẹ̀ tó wa ni ọgbà ẹ̀wọ̀n ni ìpínlẹ̀ ògùn.
Olùṣọ́-àgùntàn kan àti aya rẹ̀ ti pàdánù ẹ̀mí won nínú ìṣẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn àti ìpara-ẹni
Iwádìí tì bẹ̀rẹ̀ lori Ile Ìwòsàn ti won f’esun kan nipa gbigba kíndìnrín lọ́nà tí kò tọ́
Headline: Awon Ọlọ́pàá ti mu Obìnrin kan to gbé oògùn olóró lo s’ogbà ẹ̀wọ̀n fún ọmọ rẹ̀ tó wà ní àhámọ́
Iwádìí tì bẹ̀rẹ̀ lori Ile Ìwòsàn ti won f’esun kan nipa gbigba kíndìnrín lọ́nà tí kò tọ
The post Awon Ọlọ́pàá ti mu Obìnrin kan to gbé oògùn olóró lo s’ogbà ẹ̀wọ̀n fún ọmọ rẹ̀ tó wà ní àhámọ́… appeared first on Vanguard News.

